S/N
int64
1
436
statement
stringlengths
18
253
A1
stringclasses
2 values
A2
stringclasses
2 values
A3
stringclasses
2 values
target
stringclasses
2 values
source
stringclasses
6 values
text_origin
stringclasses
1 value
201
Zobo ni Man City fi gba aṣo lára ewúrẹ́ Liverpool, ayé polúkúmuṣu mọ́ Liverpool lówọ́ lónìí
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
BBC News
original
202
Lẹ́yìn iṣẹ́ abẹ kejì ní ikùn rẹ̀, Taiwo Awoniyi jí sáyé padà, ó kúrò ní ẹsẹ̀ kan ayé, ẹsẹ̀ kan ọ̀run
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
203
Palmer kó òtútù ká Wolves mọ́lé, níṣe ni ìkokò àti àwọn ọ̀tá Chelsea n gbọ̀n tẹnutẹnu
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
BBC News
original
204
Wo ìrànlọ́wọ́ tó yẹ kí o ṣe fún ẹni tí rọpárọsẹ̀ bá kọlù lójijì
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
205
"Ojú ọ̀nà Ikare sí Ogbagi di pàkúté ikú, ẹ̀mí arìnrìnàjò ń bọ́ púpọ̀ torí ìjàmbá ọkọ̀, ìkọlù adigunjalè àtàwọn ajínigbé"
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
206
Ẹ wo ààfin ìlù níbi tí wọ́n ti n bọ ilù gúdúgúdú tí obìnrin tó bá n ṣe nnkan oṣù kò gbọdọ̀ fọwọ́ kàn
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
207
Mo ṣiṣẹ́ abẹ, wọ́n tún pàárọ̀ itan mi nítorí àìsàn ikọ́-ife inú egungun tó mú mi'
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
208
Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa ètò ìlera Medipool tí ìjọba ṣẹ̀ṣẹ̀ buwọ́lù fún aráàlú
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
209
Lateef Adedimeji, Mercy Aigbe, àti àwọn mìí bá BBC sọ̀rọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n gba àmì ẹ̀yẹ̀ AMVCA
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
210
Agbébọn kọlu ibùdó ọmọ ogun Naijiria, wọ́n jí ọ̀pọ̀ sọ́jà gbé lọ
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
211
Ìjọba UK kéde ìlànà tuntun tí yóò bẹ́gi dínà àwọn tó fẹ́ kàwé, ṣiṣẹ́ tàbí gbé níbẹ̀
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
212
Àjọ NAPTIP kó ọmọ Naijiria 78 padà wálé lóko ẹrú láti Abidjan
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
213
Kí ni ìdí abájọ tí Pásítọ̀ Chris fi sọ pé òun máa jẹ iyọ̀ tó pọ̀ nínú oúnjẹ?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
214
Sé lóòótọ́ làwọn agbégbọn kọ lẹ́tà pé àwọn tún fẹ́ kọlu ìjọ Aguda nílùú Owo? Ohun tí a mọ̀ rèé
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
215
Ìdí rèé tí iṣẹ́ ìtọ́jú èèyàn táwọn ọmọ ilẹ̀ òkèèrè ń ṣe ní UK yóò fi dópin láìpẹ́
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
216
Wọ́n sọ iná sí ibùdó epo ní Port Sudan, aráàlú ń kérora
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
217
Bàbá Mohbad le pe ẹjọ́ tako ìdájọ́ tó tú Naira Marley àti Sam Larry sílẹ̀ - Ilé ẹjọ́
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
218
Ìyàwó ilé tó di ògbóǹtarìgì nínú ìdíje àgbáyé fáwọn èèyàn tó sán eegun
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
219
Ọkùnrin tí Salawa ń fẹ́ báyìí ń yá a lò ni, ìyàwó mi ni títí ayé - Kollington Ayinla
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
220
Oun tí aráyé ń pè ní "àṣeyọrí òjijì" náà ni ọjọ́ tí ayé ṣe pẹ̀kí pẹ̀lú òtítọ́ tí o ti ń fi lògbà láti kánrinkese
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
X
original
221
Àkókò ní ìlànà rẹ̀ tí yóò fi ṣe àfìhàn tàbí àyẹ́sí oun tí ó ní ìfaradà
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
X
original
222
Ìwọ, túbọ̀ dúró ṣinṣin pẹ̀lú òtítọ́ rẹ
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
X
original
223
Bí ẹ bá jẹ́ olùfẹ́ lítírésọ̀ Yorùbá, ó dá mi lójú pé àkàgbádùn ni ìwé ìtàn mi, tí àkọlé rẹ ń jẹ́ Ṣẹ̀gílọlá Arómirẹ́ Ògìdán yóò jẹ́ fún yín
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
X
original
224
Wo àwọn oníjàkadì inú ẹrọ̀fọ̀ tó wá di ògo àgbáyé
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
225
Lónìí ni èsì ìdánwò JAMB táwọn akẹ́kọ̀ọ́ 379,000 tún ṣe yóò jáde
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
226
Kí ló ṣokùnfà bí ẹlẹ́wọ̀n méje ṣe sá lọ lọ́gbà ẹ̀wọ̀n Osun lẹ́yìn àrọ̀ọ̀dá òjò?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
227
Ọkọ dáná sun ìyàwó àti ọmọ nítorí owó oúnjẹ
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
228
Ìtàn bí ìwà ọ̀dàlẹ̀ ṣe mú egúngún wọ ìlú Omu-Aran àti bó ṣe di àṣà
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
229
Àṣìta ìbọn 'ọlọ́pàá' ṣekú pa akẹ́kọ̀ọ́ tó ń ṣèdánwò WAEC n'Ibadan, àwọn olùfẹ̀hónúhàn gbé òkú rẹ̀ lọ ọ́fíìsì Makinde
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
230
'A kò lè sọ bóyá alága ẹgbẹ́ APC tí wọ́n jígbé l'Ondo ti kú tàbí kò tíì kú''
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
231
Mọ́gàjí Ogbomoso àti Ibadan tako àbá láti sọ Alaafin di alága láéláé ìgbìmọ̀ lọ́balọ́ba Oyo
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
232
Ẹni tí a jọ ń gbé lábẹ́ òrùlé kan ló tà mí sóko ẹrú ní Mali – Adeola, ọmọ Jumoke George
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
233
Ìfẹ̀hónúhàn wa kò lọ́wọ́ òṣèlú nínú, ìdí tí a fi wọ́de lórí ọ̀nà tí kò da rèé'
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
234
Mi ò mọ̀ pé mo lè dé ipò ọba - Owa Obokun tuntun Ilẹ̀ Ijẹsa
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
235
Ṣé lóòótọ́ ni àwọ́n jàǹdùkú kọlu Alabi Pasuma lóde eré ní Ikire?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
236
Kí ni Ààrẹ Tinubu, Peter Obi àti Kayode Fayemi bá ara wọn sọ nígbà tí wọ́n pàdé nibi ayẹyẹ Poopu ni Rome?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
237
Perimenopause: Wo àwọn ọ̀nà mẹ́fà láti mójútó ìlera lásìkò tí nǹkan oṣù obìnrin ti fẹ́ dúró
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
238
Mọ̀ nípa Opeyemi Bright, ọmọbìnrin Nàìjíríà tó di olórí ìjọba ìbílẹ̀ ní UK
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
239
Timothy Omotosho: Wo àwọn pásítọ̀ ọmọ Naijiria tó ti fìgbàkanrí ní ìṣòro òfin nílẹ̀ òkèèrè
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
240
Ọmọkùnrin tó fi mílíọ̀nù kan Náírà, owó ọ̀gá rẹ̀, ta tẹ́tẹ́ dèrò ẹ̀wọ̀n
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
241
Ìdí tí mo fi pè fún àtúntò ìgbìmọ̀ àwọn ọba l' Oyo -Seyi Makinde
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
242
Èèyàn 27 tún kú nínú ìjamba ọkọ̀ ojú omi ní Kwara
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
243
Kọngílá parí títì, àgbàrá òjò wọ́ọ lọ lọ́jọ́ kejì, Gómìnà Adeleke bá fárígá l'Osun
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
244
Ajínigbé ṣekúpa alága ẹgbẹ́ APC l'Ondo lẹ́yìn tí wọ́n kọ́kọ́ gba ₦5m owó ìtúsílẹ̀
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
245
Kí ló ṣẹlẹ̀ sí àgbà òṣèré Yemi My Lover tó fi ké gbàjarè pé òun nílò ìrànlọ́wọ́?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
246
Ìjàmbá ọkọ̀ gbẹ̀mí èèyàn méje, àwọn mẹ́rìndínlógún míì farapa
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
247
Àbọ̀ ìwádìí BBC rèé lórí ìrẹsì tí wọ́n ní ó ń pààyàn láti Seme
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
248
Njẹ́ o ti gbọ́ nípa àwọn ìlú mẹ́fà yìí níbi tí òòrùn ò kìí wọ̀ rárá?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
249
Ìdí tí mo fi sunkún nígbà tí MKO Abiola jáde láyé - Alake ilẹ̀ Ẹ̀gbá
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
250
Ogún Naira ni mo gbà fún Sinímá Ọ̀pá Ajé tó sọ mí di olókìkí – Àjan Abija
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
251
Ṣó o l'áyà! Ẹ wo bí Eniola Ajao ṣe fakọyọ lórí ètò tí BBC fi n dàn ìmọ̀ èdè Yorùbá wò
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
252
Ìfìyà-jẹ-ara ẹni ni Libya tí mo wá, mi ò tọrọ irú ẹ fún ọ̀tá mi'
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
253
Ọlọ́pàá ń lo àyẹ̀wò DNA láti ṣàwárí ìyá àwọn ọmo tí wọ́n rí nínú àpò lẹ́bá ọ̀nà
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
254
Kí ló kàn fún Simon Ekpa lẹ́yìn tí ìjọba Finland fẹ̀sùn ìdìtẹ̀mọ́jọba kàn án?
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
255
Ìbẹ̀rùbojo gbilẹ̀ lórí owó orí ẹran àgbò bí ìjọba ṣe fòfin dé kíkó àgbò lọ sórílẹ̀ èdè míì lásìkò Ileya
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
256
Ìbálòpọ̀ pẹ̀lú ìlérí góòlù - àṣírí ìwà àìtọ́ tó ń kojú àwọn ọmọdékùnrin kan láwọn ibùdó ìwakùsà tó lòdì sófin ni South Africa
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
257
Òkò ọ̀rọ̀ ń bọ́ bí Ibadan àti Oyo ṣe ń tahùn síra wọn lórí ẹni tí ipò alága ìgbìmọ̀ lọ́balọ́ba l'Oyo tọ́ sí
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
258
Ọdún ìtẹ́ ọba nìkan ni mo ti gbọdọ̀ jó lẹ́ẹ̀kan lọ́dún - Olomu ti Omu-Aran
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
259
Ohun tí a mọ̀ nípa afurasí tọ́wọ́ aráàlù tẹ̀ fẹ́sùn pé ó fẹ́ jí ọmọ gbé ní Ilorin
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
260
Pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ táa nà ní pọ̀pá, ẹníbá tabà kó lọ túnbẹ̀ ṣe
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
X
original
261
E wo nínú yín ni ó fún ọmọ yìí lóyún 🤣🤣
non-sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
X
original
262
Àgbáríjọ ẹgbẹ́ ọmọ Yorùbá ni Faransé, Ẹ ṣeun gan ni fún àmì ẹ̀yẹ ti ẹ fi dámilọ́lá.
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
X
original
263
Wàá ṣe bí ọkùnrin kí ìwọ náà tó lè jẹ́ ènìyàn pàtàkì, wá tiraka láti jẹ́ ẹni tí àwọn ènìyàn ń wárí fún un.
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
X
original
264
Àrà gbé láyé túmọ̀ sí wípé, wọ́n máa ń ra ayé gbé ní.
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
X
original
265
Ọlọ́pàá bá òkú ọmọ Nàìjíríà tí wọ́n gún pa sínú ilé ní ó ku ọ̀sẹ̀ méjì tó máa parí ìkẹ́kọ̀ọ́ nọ́ọ̀sì ní US
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
266
To ba ya won ma sope won ko ri alanu, bawo ni eniyan mase dagba lai ni opolo bio ti wun ko kere mo, won ko ma wuwa ti o ma se idina fun elomiran lati je anfaani
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
X
original
267
Tí èèyàn kò bá lówó lọ́wọ́, kí o gbìyànjú láti máa ṣe ìgbéraga
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
268
Bí ẹ o ṣe lówó lọ́wọ́ yẹn, o yẹ kẹ máa jalè ni
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
269
Oloyinbo ni '99 days for the thief, 1 day for the owner'. Ẹ o jalè fún 98 days, tó bá ti di 99th day, kí ẹ jáwọ́
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
270
Bí o ba jalè, Ọlọ́run yóò fi mú àwọn ọ̀rẹ́ẹ̀ rẹ tí wọn kò ṣàánú rẹ ni, nítorí òó ba orúkọ wọn jẹ́ ni. Àwọn ènìyàn yóò sọ wípé ọ̀rẹ́ olè, olè lòun náà
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
271
Tí o bá nta tẹ́tẹ́ lójoojúmọ́, tí o ti wá nsọ owó nù jù, kí o máa mú ọtí mọ́ọ ni.
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
272
Tí o bá ti fẹẹ pé ọgbọn ọdún láyé tí o tíì pàdé eegun tiẹ, gbé eegun eléegun ni.
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
273
Nítorí Regina Daniels n mu igbó, kò túmọ̀ wípé ọmọ burúkú ni. Ó le jẹ́ igbó tí o n mu yi ni àwọn èèyàn a fi máa bọ̀wọ̀ fún ọkọ rẹ̀.
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
274
Ẹ káre láí, Bùọ̀dá gbọ́mọgbọ́mọ😒
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
275
Olókó dógidógi, káre!
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
276
Wọn kò lè mu yín tí ẹ ba n jalè, ẹ ó fi ọpọlọ ja olè náà ni.
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
277
Bí wọ́n ṣe dájọ́ fún yín wípé ẹ máa kú ní ọjọ́ méje, ẹ yà wọ́n lẹ́nu kí ẹ kú kí ó tó di ọjọ́ méje
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
278
Tí ẹnikẹ́ni bá ní kí o má mú igbó, má ṣe dá wọn lóhùn o. Àbí kí lo fẹ́ẹ máa fi pa ìrònú rẹ? Ó kàn lè yà ẹ́ ní wèrè ni.
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Instagram
original
279
Oriogbade FC ti wá yarí kanlẹ̀ báyìí o. Kí ló ń ṣẹlẹ̀ gan-an gan-an ná ní pápá ìṣeré Emirates?
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
BBC News
original
280
Ọmọ tí yòó bá jẹ́ àṣàmú, kékeré ni yòó ti maa ṣẹnu ṣámú-ṣámú. Bùkáyọ̀ Saka, Oriogbade ooo
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
281
Gbajúgbajà akọrin Afro beat, Seun Kuti, ní àìmọ̀kan ló jẹ́ káwọn olólùfẹ́ Wizkid máa fi Wizkid wé Abami Ẹda.
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
282
Arsenal, Oriogbade FC, ṣìrìn nílé Aston Villa, àánú ikúnlẹ̀ abiyamọ ṣe wá nígbà tí ìfesewọnsệ parí
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
BBC News
original
283
Àmọ̀rí kọ́ ni ìṣòro ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Manchester United. Ẹ̀san òjóóró tí wọ́n ṣe nígbà tí Alex Ferguson jẹ́ Kóòsì wọn ló ń ké lórí wọn. Bí wọ́n ò bá múra, wọ́n máa religéètì gbẹ̀yìn..
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
Facebook
original
284
Ṣé ọ̀rọ̀ yìí kò ti di ẹni a lè mú làá lẹ̀dí mọ́ báyìí? Níbo ni Arsenal, Oriogbade, fi gbogbo góòlù yìí sí nígbà tí wọ́n kojú Liverpool?
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
BBC News
original
285
Bí olóde kò bá kú, ojúde rẹ̀ kìí hu gbẹ́gi - ẹ̀yà koríko kan.
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
286
Ríru omi òkun, kò ní kí ẹja má sùn, kò ní kí ẹja má han oorun. Bí omi òkun ṣe ń ru tó, èyí kò di ẹja lọ́wọ́ oorun
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
287
Ọmọdé tó bá mọ ọwọ́ wẹ̀, yóò bá àgbà jẹun.
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
288
Arsenal gbẹ̀san ìyà tí Aston Villa fi jẹ wọ́n lára Club Brugge tí kò mọwọ́ mẹsè.😀
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
BBC News
original
289
Àgbà òǹkọ̀wé Nàìjíríà, Wole Soyinka ní àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ àti òfurufú tí Ààrẹ Tinubu rán lọ sí orílẹ̀ èdè Benin kọ́ ló yẹ kó rán, pé Seyi Tinubu lásán ti tó.
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
BBC News
original
290
Ẹ̀yin ti Chelsea, ṣé ẹ fẹ́ pa orúkọ dá sí Anakaye FC ni?
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
BBC News
original
291
Sheikh Gumi ní káàkiri àgbáyé ni wọ́n ti máa ń bá àwọn agbébọn jíròrò láti dènà ìtàjẹ̀sílẹ̀.
non-sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
non-sarcastic
BBC News
original
292
Leeds United ló kọ́kọ́ dá ṣèríà fún Chelsea, kí Atalanta tó f'ọba leè ní ìdíje UEFA Champions League.
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
BBC News
original
293
Olúwa tó yí orúkọ Ábráhámù àti Jákọ́bù padà, yi o báwa yí orúkọ Arsenal tí 'BBC News Yoruba' ti sọ di 'Oriogbade' padà sí 'Oriade' 🙏
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
Facebook
original
294
Ayé ò! Atalanta lagi mọ́ Chelsea lórí láwọlé sùn, fa aṣọ iyì ya mọ́ Aníyìkáyé FC lára.
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
BBC News
original
295
Seyi Tinubu ló yẹ kí Aàre rán lọ ṣe ìdádúró ìdìtẹ̀gbàjọba ní orílè-èdè Benin nítorí àwọn ẹ̀ṣọ́ ààbò tó máa n tẹ̀lẹ kò níye.
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
BBC News
original
296
Wọ́n npe ibìkan ní Ìyágànkú ní Ìbàdàn. Ilé Manchester United nìyẹn, nítorí ìyá ti gan kú síwọn lára
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
Facebook
original
297
Ọlọ́tẹ̀ ni BBC Yorùbá, nítorí Man City tó kó mẹ́wàá fúnyàn lánàá, níbo ní àwọ́n kò góòlù tiwọn sí nígbà tí wọ́n kojúú Brighton
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
Facebook
original
298
Ìgbájú ìgbámú ni kẹríkẹrì bá tòdee bọ̀, Manchester United, ọwọ́ ba kórópọ̀n yín méjèèjì.
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
BBC News
original
299
Báyé bá njáyé, bí Paul Biya bá ṣì wà lórí oyè ni Cameroon, ọ̀rọ̀ bí ìyà bí ìyà kò tíì lè tán nínú ayé Manchester United
sarcastic
sarcastic
sarcastic
sarcastic
BBC News
original
300
Òjò ẹ̀sín àti ìyà tún rọ̀ lé Anfaani Adugbo, ìyẹn Manchester United, lórí lẹ́yìn tí wọ́n lè Amori lọ
sarcastic
sarcastic
non-sarcastic
sarcastic
BBC News
original